Saturday 29 October 2022

Saturday of week 30 in Ordinary Time ◼︎

or Saturday memorial of the Blessed Virgin Mary ●

(First Vespers of tomorrow, 31st Sunday in Ordinary Time)

Vespers (Evening Prayer)

Introduction (with Invitatory)

If this is not the first Hour that you are reciting today, use the version without the Invitatory Psalm instead.

Oluwa, s̩í wa ní ètè.

Àwa yóò sì yín orúko̩ Re̩.

Lord, open our lips.

And we shall praise your name.

Invitatory Psalm

Psalm 23 (24)

“Ilè̩kùn ò̩run s̩í fún Kristi nítorí pé a gbé E dìde nínú e̩ran ara” (St Irenaeus).

Let us listen for the voice of the Lord and enter into his peace.

Ti Olúwa ni ilè̩ àti è̩kún rè̩,

ayé àti gbogbo ènìyàn rè̩.

Òun ni Ó fi ìdí rè̩ so̩lè̩ lórí òkun;

Ó sì mú u dúró lórí àwo̩n odò.

Tani yóò gun òkè Olúwa lo̩?

Tani yóò dúró ní ibi mímó̩ Rè̩?

E̩ni tí o̩wó̩ rè̩ mó̩, tí o̩kàn rè̩ funfun,

tí kò lépa ohun asán,

tí kò sì búra èké tan e̩nìkejì rè̩.

E̩ni bé̩è̩ ni yóò rí ìbùkún Olúwa gbà,

àti èrè ló̩wó̩ O̩ló̩run ìgbàlà rè̩.

Bé̩è̩ ni ti àwo̩n tí ń wá a,

tí ń wá ojú O̩ló̩run Jákó̩bù.

E̩ gbé orí sókè, è̩yin ibodè,

E̩ gbéra sókè, ìlè̩kùn ayérayé,

Jé̩ kí O̩ba ògo wo̩lé.

Tá ni O̩ba ògo náà?

Olúwa, alágbára, ako̩ni,

Olúwa, ako̩gun lójú ogun.

E̩ gbé orí sókè, è̩yin ibodè,

e̩ gbéra sókè, ilè̩kùn ayérayé,

E̩ jé̩ kí O̩ba ògo wo̩lé.

Tani O̩ba ògo nàá?

Òun ni, Olúwa àwo̩n e̩gbé̩ ogun,

Òun náà ni O̩ba ògo.

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

Let us listen for the voice of the Lord and enter into his peace.

Invitatory Psalm

Psalm 23 (24)

“The gates of heaven were opened to Christ because he was lifted up in the flesh” (St Irenaeus).

Let us listen for the voice of the Lord and enter into his peace.

The Lórd’s is the éarth and its fúllness, *

the wórld and áll its péoples.

It is hé who sét it on the séas; *

on the wáters he máde it fírm.

Who shall clímb the móuntain of the Lórd? *

Who shall stánd in his hóly pláce?

The mán with clean hánds and pure héart, †

who desíres not wórthless thíngs, *

who has not swórn so as to déceive his néighbour.

He shall recéive bléssings from the Lórd *

and rewárd from the Gód who sáves him.

Súch are the mén who séek him, *

seek the fáce of the Gód of Jácob.

O gátes, lift hígh your héads; †

grow hígher, áncient dóors. *

Let him énter, the kíng of glóry!

Whó is the kíng of glóry? †

The Lórd, the míghty, the váliant, *

the Lórd, the váliant in wár.

O gátes, lift hígh your héads; †

grow hígher, áncient dóors. *

Let him énter, the kíng of glóry!

Who is hé, the kíng of glóry? †

Hé, the Lórd of ármies, *

hé is the kíng of glóry.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

Let us listen for the voice of the Lord and enter into his peace.

________

Hymn

In the beginning God created heaven,

The dark and empty earth;

His Spirit moved across the sombre waters

And stirred them with his breath.

Then God created light, and with its coming

The dark was swept away;

The morning came, and then the quiet evening:

The end of God’s first day.

To God the Father of the world give glory,

With Christ his only Son,

Who with the Spirit govern all creation:

Blest Trinity in One.

Hymn

In the beginning God created heaven,

The dark and empty earth;

His Spirit moved across the sombre waters

And stirred them with his breath.

Then God created light, and with its coming

The dark was swept away;

The morning came, and then the quiet evening:

The end of God’s first day.

To God the Father of the world give glory,

With Christ his only Son,

Who with the Spirit govern all creation:

Blest Trinity in One.

Stanbrook Abbey Hymnal

________

Psalm 112 (113)

E̩ yin orúko̩ Olúwa

“Ó lé àwo̩n alágbára kúrò lórí ìté̩ Ó sì gbé àwo̩n onírè̩lè̩ sóké” (Lk 1:52).

From the rising of the sun to its setting, great is the name of the Lord.

È̩yin ìránńs̩é̩ Olúwa, e̩ yìn ín.

E̩ yin orúko̩ Olúwa.

Ìbùkún ni fún orúko̩ Olúwa

nísisìyí àti títí láéláé.

Láti ilà-oòrùn títí dé ìwò̩-oòrùn,

ìbùkún ni fún orúko̩ Olúwa.

Olúwa ga lórí gbogbo orílè̩-èdè.

Ògo Rè̩ ga lórí gbogbo ò̩run.

Tani ó dàbí Olúwa O̩ló̩run wa?

e̩ni tí Ó gúnwà lórí ìté̩ Rè̩,

tí Ó de̩ra Rè̩ lókè

láti bojúwo ò̩run òun ayé?

Ó gbé aláìni dìde kúrò nínú eruku,

Ó sì gbé òtòs̩ì kúró lórí ààtàn.

láti mú wo̩n jókòó

láàárín àwo̩n aládé,

pè̩lú àwo̩n aládé ènìyàn Rè̩.

Ó fi ìdílé fún obìnrin àgàn,

Ó sì mú inú rè̩ dùn pè̩lú o̩mo̩kùnrin!

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

From the rising of the sun to its setting, great is the name of the Lord.

Psalm 112 (113)

Praise of the Lord\’s name

“He put down princes from their thrones and exalted the lowly” (Lk 1:52).

From the rising of the sun to its setting, great is the name of the Lord.

Práise, O sérvants of the Lórd, *

práise the náme of the Lórd!

May the náme of the Lórd be bléssed *

both nów and for évermóre!

From the rísing of the sún to its sétting *

práised be the náme of the Lórd!

Hígh above all nátions is the Lórd, *

abóve the héavens his glóry.

Whó is like the Lórd, our Gód, *

who has rísen on hígh to his thróne

yet stóops from the héights to look dówn, *

to look dówn upon héaven and éarth?

From the dúst he lífts up the lówly, *

from his mísery he ráises the póor

to sét him in the cómpany of prínces, *

yés, with the prínces of his péople.

To the chíldless wífe he gives a hóme *

and gláddens her héart with chíldren.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

From the rising of the sun to its setting, great is the name of the Lord.

Psalm-Prayer

Almighty Father, we praise and bless your name and ask you to join us together through your enduring love in the bosom of Mother Church.

Or:

Lord Jesus, Word of God, surrendering the brightness of your glory you became man so that we might be raised from the dust to share your very being. May there be innumerable children of the Church to offer homage to your name from the rising of the sun to its setting.

________

Psalm 115 (116B)

Ìdúpé̩ nínú Té̩mpélì

“E̩ jé̩ kí a tipasè̩ Jésù máa rúbo̩ ìyìn sí O̩ló̩run” (Heb 13:15).

I will take the chalice of salvation, and I will call on the name of the Lord.

Mo ní ìgbàgbó̩! Àní bí mo ti wí pé:

‘Ó ni mí lára púpò̩ jù.’

Mo wí nínú ìpayà mi pé:

‘Ènìyàn kò s̩e é gbé̩kè̩lé.’

Báwo ni kí n s̩e s̩è̩san fún Olúwa

fún gbogbo oore tó s̩e fún mi?

Èmi yóò gbé ife ìgbàlà sókè,

èmi yóò ké pe orúko̩ Olúwa.

Èmi yóò san è̩jé̩ mi fún Olúwa

níwájú gbogbo àwo̩n ènìyàn Rè̩.

Iyebíye níwájú Olúwa

ni ikú àwo̩n ò̩ré̩ Rè̩.

Jàre! Olúwa, ìránńs̩é̩ Re̩ ni mo ń s̩e,

ìránńs̩é̩ Re̩ ni mí, o̩mo̩ ìránńs̩é̩bìnrin Re̩,

Ìwo̩ ti tú è̩wò̩n tí a fi dè mi.

Èmi yóò rú e̩bo̩ o̩pé̩ sí O̩,

èmi yóò ké pe orúko̩ Olúwa.

Èmi yóò san è̩jé̩ mi fún Olúwa

níwájú gbogbo àwo̩n ènìyàn Rè̩,

ní àgbàlá ilé Olúwa,

láàárín re̩, Jérúsálé̩mù!

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

I will take the chalice of salvation, and I will call on the name of the Lord.

Psalm 115 (116B)

Thanksgiving in the Temple

“Through him [Christ], let us offer God an unending sacrifice of praise” (Heb 13:15).

I will take the chalice of salvation, and I will call on the name of the Lord.

I trústed, éven when I sáid: *

‘I am sórely afflícted,’

and whén I sáid in my alárm: *

‘No mán can be trústed.’

How cán I repáy the Lórd *

for his góodness to mé?

The cúp of salvátion I will ráise; *

I will cáll on the Lórd’s name.

My vóws to the Lórd I will fulfíl *

befóre all his péople.

O précious in the éyes of the Lórd *

is the déath of his fáithful.

Your sérvant, Lord, your sérvant am Í; *

you have lóosened my bónds.

A thánksgiving sácrifice I máke; *

I will cáll on the Lórd’s name.

My vóws to the Lórd I will fulfíl *

befóre all his péople,

in the cóurts of the hóuse of the Lórd, *

in your mídst, O Jerúsalem.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

I will take the chalice of salvation, and I will call on the name of the Lord.

Psalm-Prayer

Lord, accept the prayers of your faithful people. Help us always to offer you a sacrifice of praise. Quickly break the bonds that hold your children down, and we will fulfil our vows and praise you every day.

Or:

Father, precious in your sight is the death of the saints, but precious above all is the love with which Christ suffered to redeem us. In this life we fill up in our own flesh what is still lacking in the sufferings of Christ; accept this as our sacrifice of praise, and we shall even now taste the joy of the new Jerusalem.

________

Canticle

Philippians 2

Krístì, e̩rú O̩ló̩run

The Lord Jesus humbled himself: therefore God has highly exalted him for ever.

Bí ó tilè̩ jé̩ pé Ó ní ìwà kan náà pè̩lú O̩ló̩run,

Jésù kò wo mó̩ ipò Rè̩ yìí

S̩ùgbó̩n ó bó̩ ògo rè̩ sílè̩,

ó sì so̩ ara-rè̩ di e̩rú,

tí a sì bí i ní ènìyàn.

Ó hùwà ènìyàn,

Ó tún re̩ ara Rè̩ sílè̩,

Ó gbó̩ràn sí O̩ló̩run lé̩nu,

Ó sì gbà láti kú,

àní ikú lórí àgbélébùú pàápàá.

Nítorí náà ni O̩ló̩run s̩e gbé e ga,

tí Ó sì fún un ní orúko̩ kan tó borí gbogbo orúko̩,

Tó fi jé̩ pé ní orúko̩ Jésù

ní gbogbo eékún gbó̩dò̩ kúnlè̩

ní òkè ò̩run, lórí ayé àti ní ìsàlè̩ ilè̩,

Tí gbogbo ahó̩n sì gbó̩dò̩ kéde pé:

OLÚWA ni Jésù Krístì nínú ògo O̩ló̩run Bàbá.

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

The Lord Jesus humbled himself: therefore God has highly exalted him for ever.

Canticle

Philippians 2

Christ, God\’s servant

The Lord Jesus humbled himself: therefore God has highly exalted him for ever.

Though he was in the form of God, *

Jesus did not count equality with God a thing to be grasped.

He emptied himself, †

taking the form of a servant, *

being born in the likeness of men.

And being found in human form, †

he humbled himself and became obedient unto death, *

even death on a cross.

Therefore God has highly exalted him *

and bestowed on him the name which is above every name,

That at the name of Jesus every knee should bow, *

in heaven and on earth and under the earth,

And every tongue confess that Jesus Christ is Lord, *

to the glory of God the Father.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

The Lord Jesus humbled himself: therefore God has highly exalted him for ever.

________

Scripture Reading

Hebrews 13:20-21

Kí O̩ló̩run àlááfíà tó mú Jésù Olúwa wa jíǹde kúrò nínú òkú, E̩ni tó di Olùs̩ó̩ Àgùntàn ńlá nípa è̩jè̩ májè̩mú ayérayé, kí Ó fún un yín lágbára láti s̩e ìfé̩ e̩ Rè̩ nínú ohun rere gbogbo, kí Ó sì máa s̩e ohun tó jé̩ àté̩wó̩gbà nínú wa, nípasè̩ Jésù Krístì, E̩ni tí a óò máa fi ògo fún títí ayé àìnípè̩kun. Àmín.

Scripture Reading

Hebrews 13:20-21

I pray that the God of peace, who brought our Lord Jesus back from the dead to become the great Shepherd of the sheep by the blood that sealed an eternal covenant, may make you ready to do his will in any kind of good action; and turn us all into whatever is acceptable to himself through Jesus Christ, to whom be glory for ever and ever, Amen.

________

Short Responsory

How great are your works, O Lord.

How great are your works, O Lord.

In wisdom you have created them all.

How great are your works, O Lord.

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩ àti fún È̩mí Mímó̩.

How great are your works, O Lord.

Short Responsory

How great are your works, O Lord.

How great are your works, O Lord.

In wisdom you have made them all.

How great are your works, O Lord.

Glory be to the Father and to the Son and to the Holy Spirit.

How great are your works, O Lord.

________

Canticle

Magnificat

È̩mí mi ń yò̩ sí O̩ló̩run

‘Zacchaeus, come down. Hurry, because I must stay at your house today.’ And he hurried down and welcomed him joyfully. (Year C)

Or: You have only one master and he is in heaven: Christ, the Lord.

O̩kàn mi yin Olúwa lógo

È̩mí mi sì ń yò̩ sí O̩ló̩run olùgbàlà mi

Nítorí Ó s̩íjú wo ìwà ìrè̩lè̩ o̩mo̩bìnrin ò̩dò̩ Rè̩,

sá kíyèsí i, láti ìsinsìnyí lo̩

gbogbo ènìyàn ni yóò máa pè mí ní alábùkún fún.

Nítorí Olódùmarè ti s̩e ohun ribiribi fún mi,

Mímó̩ sì ni orúko̩ Rè̩.

Àánú Rè̩ ń be̩ fún àwo̩n tó bè̩rù Rè̩ láti ìran dé ìran.

Ó ti fi agbára apá Rè̩ hàn;

Ó ti tú àwo̩n gíga ká nínú ìgbéraga o̩kàn wo̩n.

Ó ti fa àwo̩n alágbára o̩ló̩kàn gíga lulè̩;

Ó sì ti gbé àwo̩n onírè̩lè̩ o̩kàn sókè

Ó ti kún àwo̩n tálákà fún ohun dáradára;

Ó sì ti lé àwo̩n o̩ló̩rò̩ padà ló̩wó̩ òfo.

Ó ti gba Ísráé̩lì o̩mo̩ ò̩dò̩ Rè̩ sábé̩ ààbò Rè̩ ní ìrántí àánú Rè̩.

Gé̩gé̩ bí ó ti s̩e ìlérí fún àwo̩n Baba wa,

fún Ábráhámù àti fún ìran rè̩ títí láé.

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

‘Zacchaeus, come down. Hurry, because I must stay at your house today.’ And he hurried down and welcomed him joyfully. (Year C)

Or: You have only one master and he is in heaven: Christ, the Lord.

Canticle

Magnificat

My soul rejoices in the Lord

‘Zacchaeus, come down. Hurry, because I must stay at your house today.’ And he hurried down and welcomed him joyfully. (Year C)

Or: You have only one master and he is in heaven: Christ, the Lord.

My soul glórifies the Lórd, *

my spirit rejóices in Gód, my Sáviour.

He looks on his sérvant in her lówliness; *

henceforth all áges will cáll me bléssed.

The Almíghty works márvels for me. *

Hóly his náme!

His mércy is from age to áge, *

on thóse who féar him.

He púts forth his árm in stréngth *

and scátters the proud-héarted.

He casts the míghty from their thrónes *

and ráises the lówly.

He fills the stárving with good thíngs, *

sends the rích away émpty.

He protects Ísrael, his sérvant, *

remémbering his mércy,

the mercy prómised to our fáthers, *

to Ábraham and his sóns for éver.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

‘Zacchaeus, come down. Hurry, because I must stay at your house today.’ And he hurried down and welcomed him joyfully. (Year C)

Or: You have only one master and he is in heaven: Christ, the Lord.

________

Prayers and intercessions

Christ our Lord is mindful of all who need him, and does great things for love of them. Let us not be afraid to ask him for all our needs.

Show us your loving kindness.

Lord, we know that the good things we have received today have come as a gift from you:

may we receive them with thankfulness and learn how to give.

Show us your loving kindness.

Saviour and light of all people, keep missionaries in your special care:

may the light of your Spirit burn strongly in them.

Show us your loving kindness.

Grant that the world may be filled with the knowledge of your truth;

help us to carry out all you have called us to do.

Show us your loving kindness.

You healed the sickness and pain of your brothers:

Bring healing and comfort to the spirit of man.

Show us your loving kindness.

Give rest to the faithful departed;

and bring them to praise you in eternity.

Show us your loving kindness.

Prayers and intercessions

Christ our Lord is mindful of all who need him, and does great things for love of them. Let us not be afraid to ask him for all our needs.

Show us your loving kindness.

Lord, we know that the good things we have received today have come as a gift from you:

may we receive them with thankfulness and learn how to give.

Show us your loving kindness.

Saviour and light of all people, keep missionaries in your special care:

may the light of your Spirit burn strongly in them.

Show us your loving kindness.

Grant that the world may be filled with the knowledge of your truth;

help us to carry out all you have called us to do.

Show us your loving kindness.

You healed the sickness and pain of your brothers:

Bring healing and comfort to the spirit of man.

Show us your loving kindness.

Give rest to the faithful departed;

and bring them to praise you in eternity.

Show us your loving kindness.

________

Our Father, who art in heaven,

hallowed be thy name.

Thy kingdom come.

Thy will be done on earth, as it is in heaven.

Give us this day our daily bread,

and forgive us our trespasses,

as we forgive those who trespass against us,

and lead us not into temptation,

but deliver us from evil.

________

God of power and mercy,

by whose grace your people give you praise and worthy service,

save us from faltering

on our way to the joys you have promised.

Through our Lord Jesus Christ, your Son,

who lives and reigns with you in the unity of the Holy Spirit,

God, for ever and ever.

Amen.

God of power and mercy,

by whose grace your people give you praise and worthy service,

save us from faltering

on our way to the joys you have promised.

Through our Lord Jesus Christ, your Son,

who lives and reigns with you in the unity of the Holy Spirit,

God, for ever and ever.

Amen.

________

The Lord bless us, and keep us from all evil, and bring us to everlasting life.

Amen.