Daily Reading

Àwa yóò sì yín orúko̩ Re̩.

Lord, open our lips.

And we shall praise your name.

Invitatory Psalm

Psalm 99 (100)

“Olúwa pe gbogbo àwa tí Ó ti gbà là kí a ko̩ orin ìs̩é̩gun” (St Athanasius).

Come, let us adore the Lord, for he is our God.

E̩ yin Olúwa, gbogbo àgbáyè,

e̩ fi tayò̩tayò̩ sin Olúwa,

e̩ lo̩ síwájú Rè̩ pè̩lú orin ayò̩!

E̩ mò̩ pé Olúwa ni O̩ló̩run,

Òun ni Ó dá wa, àwá sì jé̩ tirè̩;

àwá jé̩ ènìyàn Rè̩ àti agbo àgùntàn Rè̩,

e̩ fi o̩pé̩ fún un, e̩ fi ìyìn fún orúko̩ Rè̩!

Lóòtó̩ Olúwa dára,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

Come, let us adore the Lord, for he is our God.

Invitatory Psalm

Psalm 99 (100)

“The Lord calls all those he has redeemed to sing a hymn of victory” (St Athanasius).

Come, let us adore the Lord, for he is our God.

Cry out with jóy to the Lórd, all the éarth. †

Know that hé, the Lórd, is Gód. †

Thursday 6 October 2022

Thursday of week 27 in Ordinary Time ◼︎

or Saint Bruno, Priest ●

or Blessed Marie-Rose Durocher ●

Vespers (Evening Prayer)

Introduction (with Invitatory)

Oluwa, s̩í wa ní ètè.

Àwa yóò sì yín orúko̩ Re̩.

Lord, open our lips.

And we shall praise your name.

Invitatory Psalm

Psalm 99 (100)

“Olúwa pe gbogbo àwa tí Ó ti gbà là kí a ko̩ orin ìs̩é̩gun” (St Athanasius).

Come, let us adore the Lord, for he is our God.

E̩ yin Olúwa, gbogbo àgbáyè,

e̩ fi tayò̩tayò̩ sin Olúwa,

e̩ lo̩ síwájú Rè̩ pè̩lú orin ayò̩!

E̩ mò̩ pé Olúwa ni O̩ló̩run,

Òun ni Ó dá wa, àwá sì jé̩ tirè̩;

àwá jé̩ ènìyàn Rè̩ àti agbo àgùntàn Rè̩,

E̩ lo̩ dúpé̩ lé̩nu ò̩nà Rè̩,

e̩ wo̩nú ilé Rè̩ pè̩lú orin,

e̩ fi o̩pé̩ fún un, e̩ fi ìyìn fún orúko̩ Rè̩!

Lóòtó̩ Olúwa dára,

títí láé ni ìfé̩ Rè̩,

òdodo Rè̩ fún títí ayérayé.

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

Come, let us adore the Lord, for he is our God.

Invitatory Psalm

Psalm 99 (100)

“The Lord calls all those he has redeemed to sing a hymn of victory” (St Athanasius).

Come, let us adore the Lord, for he is our God.

Cry out with jóy to the Lórd, all the éarth. †

Sérve the Lórd with gládness. *

Come befóre him, sínging for jóy.

Know that hé, the Lórd, is Gód. †

He máde us, we belóng to hím, *

we are his péople, the shéep of his flóck.

Gó within his gátes, giving thánks. †

Enter his cóurts with sóngs of práise. *

Give thánks to him and bléss his náme.

Indéed, how góod is the Lórd, †

etérnal his mérciful lóve. *

He is fáithful from áge to áge.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

Come, let us adore the Lord, for he is our God.


\"\"

When God had filled the earth with life

And blessed it, to increase,

Then cattle dwelt with creeping things,

And lion with lamb, at peace.

He gave them vast, untrodden lands,

With plants to be their food;

Then God saw all that he had made

And found it very good.

Praise God the Father of all life,

His Son and Spirit blest,

By whom creation lives and moves,

In whom it comes to rest.

Stanbrook Abbey Hymnal

________

Psalm 131:1-10

Ìlérí O̩ló̩run sí ilé Dáfídì

“Olúwa O̩ló̩run yóò fún un ní ìté̩ Dáfídì bàbá Rè̩” (Lk 1:32).

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.

Ránti Dafídì, Olúwa,

àti gbogbo ìs̩òro tí ó faradà,

ìbúra tí ó s̩e fún Olúwa,

àti è̩jé̩ tí ó jé̩ fún Alágbára Jákó̩bù.

‘Èmi kò ní í wo̩ abé̩ òrùlé mi,

èmi kò ní í gun ibùsùn mi,

èmi kò ni í fi orun kan ojú mi,

ìpénpéjù mi kò sì ní í tòògbé

títí èmi ó fi rí ibì kan fún Olúwa,

ibùgbé kan fún Alágbára jùlo̩ Jákó̩bù.’

Kíyèsí i, a gbúró àpótí májè̩mú ní Éfrátà,

a rí i ní Pápá-Onígi!

Jé̩ kí a lo̩ ibi tó ń gbé;

jé̩ kí a kúnlè̩ níwájú ohun ìtìsè̩ Rè̩.

Dìdé, Olúwa, wá síbi ìsimi Re̩,

Ìwo̩ àti àpótí è̩rí agbára Re̩.

Àwo̩n àlùfáà Re̩ yóò gbé ìwà mímó̩ wò̩,

àwo̩n onígbàgbó̩ Re̩ yóò hó ìhó ayò̩,

nítorí Dáfídì ìránńs̩é̩ Re̩,

má s̩e ko̩ e̩ni òróró Re̩ sílè̩.

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.

Psalm 131 (132):1-10

God\’s promise to the house of David

“The Lord God will give him the throne of David his father” (Lk 1:32).

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.

O Lórd, remémber Dávid *

and áll the many hárdships he endúred,

the óath he swóre to the Lórd, *

his vów to the Stróng One of Jácob.

‘I will not énter the hóuse where I líve *

nor gó to the béd where I rést.

I will gíve no sléep to my éyes, *

to my éyelids I will gíve no slúmber

till I fínd a pláce for the Lórd, *

a dwélling for the Stróng One of Jácob.’

At Éphrata we héard of the árk; *

we fóund it in the pláins of Yéarim.

‘Let us gó to the pláce of his dwélling; *

let us gó to knéel at his fóotstool.’

Go up, Lórd, to the pláce of your rést, *

yóu and the árk of your stréngth.

Your príests shall be clóthed with hóliness; *

your fáithful shall ríng out their jóy.

For the sáke of Dávid your sérvant *

dó not rejéct your anóinted.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.