Be sympathetic; love the brothers and sisters, have compassion

When God had filled the earth with life

And blessed it, to increase,

Then cattle dwelt with creeping things,

And lion with lamb, at peace.

He gave them vast, untrodden lands,

With plants to be their food;

Then God saw all that he had made

And found it very good.

Praise God the Father of all life,

His Son and Spirit blest,

By whom creation lives and moves,

In whom it comes to rest.

Stanbrook Abbey Hymnal

________

Psalm 131:1-10

Ìlérí O̩ló̩run sí ilé Dáfídì

“Olúwa O̩ló̩run yóò fún un ní ìté̩ Dáfídì bàbá Rè̩” (Lk 1:32).

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.

Ránti Dafídì, Olúwa,

àti gbogbo ìs̩òro tí ó faradà,

ìbúra tí ó s̩e fún Olúwa,

àti è̩jé̩ tí ó jé̩ fún Alágbára Jákó̩bù.

‘Èmi kò ní í wo̩ abé̩ òrùlé mi,

èmi kò ní í gun ibùsùn mi,

èmi kò ni í fi orun kan ojú mi,

ìpénpéjù mi kò sì ní í tòògbé

títí èmi ó fi rí ibì kan fún Olúwa,

ibùgbé kan fún Alágbára jùlo̩ Jákó̩bù.’

Kíyèsí i, a gbúró àpótí májè̩mú ní Éfrátà,

a rí i ní Pápá-Onígi!

Jé̩ kí a lo̩ ibi tó ń gbé;

jé̩ kí a kúnlè̩ níwájú ohun ìtìsè̩ Rè̩.

Dìdé, Olúwa, wá síbi ìsimi Re̩,

Ìwo̩ àti àpótí è̩rí agbára Re̩.

Àwo̩n àlùfáà Re̩ yóò gbé ìwà mímó̩ wò̩,

àwo̩n onígbàgbó̩ Re̩ yóò hó ìhó ayò̩,

nítorí Dáfídì ìránńs̩é̩ Re̩,

má s̩e ko̩ e̩ni òróró Re̩ sílè̩.

Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩

àti fún È̩mí Mímó̩.

Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,

o ń be̩ nísinsìnyí,

bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo

ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.

Psalm 131 (132):1-10

God\’s promise to the house of David

“The Lord God will give him the throne of David his father” (Lk 1:32).

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.

O Lórd, remémber Dávid *

and áll the many hárdships he endúred,

the óath he swóre to the Lórd, *

his vów to the Stróng One of Jácob.

‘I will not énter the hóuse where I líve *

nor gó to the béd where I rést.

I will gíve no sléep to my éyes, *

to my éyelids I will gíve no slúmber

till I fínd a pláce for the Lórd, *

a dwélling for the Stróng One of Jácob.’

At Éphrata we héard of the árk; *

we fóund it in the pláins of Yéarim.

‘Let us gó to the pláce of his dwélling; *

let us gó to knéel at his fóotstool.’

Go up, Lórd, to the pláce of your rést, *

yóu and the árk of your stréngth.

Your príests shall be clóthed with hóliness; *

your fáithful shall ríng out their jóy.

For the sáke of Dávid your sérvant *

dó not rejéct your anóinted.

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

Your faithful shall ring out their joy as they enter your dwelling-place, Lord.

________

Psalm 131 (132)

The Lord has chosen Sion as his dwelling-place.

Olúwa ti búra fún Dáfídì,

kò sì ní í pò̩rò̩dà láé:

‘O̩mo̩kùnrin bíbí inú re̩

ni èmi yóò gbé kalè̩ lórí ité̩ re̩.

Bí wó̩n bá pa májè̩mú mi mó̩,

àti òfin mi tí mo fi kó̩ wo̩n ní òtító̩,

àwo̩n o̩mo̩ wo̩n yóò jo̩ba bákan náà

lórí ìté̩ re̩ láti ìrán dé ìran.’

Nítorí Olúwa ti yan Síónì,

Ó fé̩ e̩ fún ibùjòkó Rè̩:

‘Níbí ni ìbùjókòó mi títí láé,

níhìn-ín ni mo yàn láti máa gbé.

‘Èmi yóò fi ire bùkún fún àwo̩n olódodo Rè̩,

èmi yóò fi oúnje̩ té̩ àwo̩n tálákà Rè̩ ló̩rùn.

Èmi yóò fi ìgbàlà wo̩ àwo̩n àlùfáà Rè̩,

àwo̩n onígbàgbó̩ Rè̩ yóò sì máa yò̩ s̩è̩s̩è̩.

‘Níbè̩ ni èmi yóò ti gbé

ìràn kan dìde fún Dáfídì,

tí n yóò pèsè fìtílà kan fún Mèsíà mi.

Èmi yóò kó ìtìjú bo àwo̩n ò̩tá Rè̩,

tí adé orí Rè̩ yóò lógo.

Psalm 131 (132):11-18

The Lord has chosen Sion as his dwelling-place.

The Lórd swore an óath to Dávid; *

he wíll not go báck on his wórd:

‘A són, the frúit of your bódy, *

will I sét upón your thróne.

‘If they kéep my cóvenant in trúth *

and my láws that Í have táught them,

their sóns álso shall rúle *

on your thróne from áge to áge.’

For the Lórd has chósen Síon; *

he has desíred it fór his dwélling:

‘Thís is my résting-place for éver; *

hére have I chósen to líve.

‘I will gréatly bléss her próduce, *

I will fíll her póor with bréad.

I will clóthe her príests with salvátion *

and her fáithful shall ríng out their jóy.

‘Thére David’s stóck will flówer; *

I will prepáre a lámp for my anóinted.

I will cóver his énemies with sháme *

but on hím my crówn shall shíne.’

Glory be to the Father and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

The Lord has chosen Sion as his dwelling-place.

Psalm-Prayer

You are our King, Lord God. Help us to find a place for you in our hearts. Clothe your priests with saving power, fill the needy with bread, and let your holiness shine on us all.

Or:

You have chosen the new Zion as your dwelling place, Lord God, the Church as your place of rest. You have kindled in her a lamp that will burn brightly for ever before Christ your Anointed One. Make our hearts your tabernacle, clothe your priests with justice, your faithful with holiness and give bread to the poor. May all rejoice with you in heaven.

________

Canticle

Apocalypse 11

Ìdájó̩

The Lord has given him power and honour and empire, and all peoples will serve him.

A dúpé̩ fún O̩, Olúwa O̩ló̩run Olódùmarè,

e̩ni tí Ó wà, tí Ó sì ti wà,

nítorí Ìwo̩ ti gba agbára ńlá Re̩

tí O sì ń jo̩ba.

Inú àwo̩n orílè̩-èdè ru

s̩ùgbó̩n ìbínú re̩ dé bá wo̩n,

àkókò ti dé láti dá àwo̩n òkú lé̩jó̩;

nígbà tí a ó s̩è̩san fún àwo̩n ìránńs̩é̩ re̩,

wòlíì àti àwo̩n ènìyàn mímó̩,

àti àwo̩n tó bè̩rù orúko̩ ò̩ Re̩,

ní e̩ni kékeré àti àgbà,

Láti ìsinsìnyìí lo̩ ni O̩ló̩run wa ti gba ìs̩é̩gun,

àgbára, ìjo̩ba àti às̩e̩ fún Krístì Rè̩

nítorí pé a ti lé olùfisùn àwo̩n ará wa jáde,

e̩ni tí ń fi è̩sùn kàn wó̩n tò̩sán tòru níwájú O̩ló̩run wa.

Wó̩n ti fúnrawo̩n s̩é̩gun rè̩

nípa è̩jè̩ Ò̩dó̩-Àgùntàn náà

àti nípa ìjé̩rìí ikú wo̩n nítorí ìgbàgbó̩,

nítorí wo̩n kò sì jé̩ kí ìfé̩ láti wà láàyè dá ikú wo̩n dúró.

Nítorí náà kí è̩yin ò̩run yò̩

àti gbogbo ohun tí ń be̩ níbè̩.

The Judgement

The Lord has given him power and honour and empire, and all peoples will serve him.

We give thanks to you, Lord God Almighty, *

who are and who were,

that you have taken your great power *

and begun to reign.

The nations raged, *

but your wrath came,

and the time for the dead to be judged, *

for rewarding your servants, the prophets and saints,

and those who fear your name, *

both small and great.

Now the salvation and the power †

and the kingdom of our God *

and the authority of his Christ have come,

for the accuser of our brethren has been thrown down, *

who accuses them day and night before our God.

And they have conquered him *

by the blood of the Lamb

and by the word of their testimony, *

for they loved not their lives even unto death.

Rejoice, then, O heaven, *

and you that dwell therein.

Glory be to the Father

and to the Son

and to the Holy Spirit,

as it was in the beginning,

is now, and ever shall be,

world without end.

Amen.

The Lord has given him power and honour and empire, and all peoples will serve him.

Scripture Reading

1 Peter 3:8-9

Kí gbogbo yín ní è̩mí ìs̩ò̩kan pè̩lú è̩mí agbò̩rò̩dùn, kí e̩ ní ìfé̩ o̩mo̩ ìyá láàrín ara yín pè̩lú ojú àánú àti è̩mí ìrè̩lè̩. Kí e̩ má s̩e fi ibi san ibi, tàbí èébú fún èébú, s̩ùgbó̩n s̩e ni kí e̩ máa súre fún àwo̩n ènìyàn nítorí iye̩n ni a pè yín fún, kí e̩ bàa lè jogún ìbùkún.

Scripture Reading

1 Peter 3:8-9

➡️You should all agree among yourselves and be sympathetic; love the brothers, have compassion and be self-effacing. Never pay back one wrong with another, or an angry word with another one; instead, pay back with a blessing. That is what you are called to do, so that you inherit a blessing yourself.